Adura wiwo ile egbin

Pelu oruko Olohun, Ire Olohun Allaah dajudaju emi sadi O kuro nibi awon ako alujannu ati awon abo re. (1) .................... (1) Al-Bukhaari lo gbe e jade, 1/45, pelu number 142, ati Muslim, 1/283, pelu number 375, pelu alekun: (mo bere pelu oruko Olohun) ni ibere re, Sahiid omo Mansuur lo gbe e jade. wo Fat'hul Baari 1/244

API