Adura ti a fi maa n koju ota abi eni ti oni agbara

Olohun, a n fi O si oke aya won ki won ma le de odo wa rara, a si fi o wa isora kuro nibi aburu won

Olohun Iwo ni Alafeyinti mi, Iwo ni Alaranse mi, Iwo ni n o fi maa ti ete ota danu, Iwo ni n o si fi bori won, Iwo ni n o si fi ma aba won ja

Olohun to wa, mondala Re ni Alamojuto.

API