Adura ibanikedun

Titi Olohun ni nkan ti O ba gba, ti E naa ni ohun ti O ba fun ni, gbogbo nkan wa lodo Olohun pelu akoko kan pato, yaa se suuru ki o si fi esan ti sodo Olohun.

API