Adura sise ti a ba fe bo oku loju

Olohun forijin lagbaja (a o daruko re) gbe ipo re ga laarin awon olumona, se arole fun un lori awon ti o seku ninu awon aromodomo re, fori jin wa ati oun naa, Iwo Olohun Oba agbanlaaye, ba ni fe saare re fun un, ki O si ba ni tan imole sinu saare re fun un.

API