Mima gbe Olohun tobi nigbati o ba de ibi okuta dudu

Anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – rokirika ile Olohun lori rakunmi gbogbo igba ti o ba ti de ibi origun yio na nkan ti o wa ni owo re si i yio si gbe Olohun tobi.

API