Kiki eniti o bimo ati esi ti eniti obi mo naa maa fo

Olohun yio fi ibukun si ore ti O ta o yii , o dupe fun eniti O fun o ni ore naa, omo naa yio si dagba, Olohun yio ro o ni oro daadaa omo naa

API