Gbigbe Olohun tobi ati si se afomo fun Un nigbati eeyan ba nrin irinajo

Jaabir so – ki Olohun yonu si i -: A je enikan ti o je wipe ti a ba gun oke, a maa gbe Olohun tobi, ti a ba si so kale a maa se afomo fun Un.

API