Ninu Adura ti a maa nse nigba ti ojo ba ti poju

Iwo Olohun, awon ayika wa ni ki o maa ro o si ma se ro o le wa lori, je ki o maa ro sori awon ile giga ati awon oke keekeekee, ati si inu awon afonufoji ati sara awon itakun igi.

API