Adura alaawe nigbati ounje ba de ti ko si tii sinu

Ti won ba pe enikookan yin si ounje ki o ya je ipe, ti o ba wa je eniti o gba aawe ki o se adura, ti o ba wa je eniti ko gba aawe ki o yaa jeun. Itumo (falyusolli) ni pe: ki o ya se adura.

API