Adura ti a ma nse nigbati a ba ri yiyo eso

Ire Olohun Oba, fi alubarika sibi eso wa fun wa, wa tun fi alubarika si ilu wa fun wa, wa tun fi alubarika sibi soohu wa fun wa, wa tun fi alubarika sibi mudu wa fun wa.

API