Sise Atayah

(Gbogbo kiki ti Allah ni ati gbogbo eyin ati ohun gbogbo ohun ti odara ola Olohun kio maa ba e ire anabi ati ike Allah ati alubarika Re, ola ki o ma bawa ati awon erusin Allah ti won je eni ti E. Mojeri pe ko si eniti ijosin ayafi Allah, mosi jeri pe anabi Muhammed eru Re ni atipe ojise Re ni) (1) .................................... (1) Al-Bukhaari pelu Al-Fat'hu, 2/311, pelu number 831, ati Muslim, 1/301, pelu number 402.

API