Adura eniti won ba fi adanwo kan

Odo Olohun ni awa ti wa, odo Re ni a o si seri pada, Olohun, san mi ni esan nibi adanwo ti o sele si mi yii, ohun ti o dara ju u lo ni ki o fi ropo fun mi

API