Adura eniti royi royi ba se ninu igbabo yio maa se

Yio fi Olohun wa isora Yio kuro nibi ohun ti o nse royi royi si

Yio si so bayi wipe: Mo ni igbagbo si Olohun ati awon ojise Re

Yio ke oro Olohun to ni: Olohun ni Oba akoko, Oun ni Olugbeyin, Oun ni eni ti O han, Oun ni eniti O pamo, Oun ni eniti O ni mimo pelu gbogbo nkan

API