Adura lati wo aso tuntun

Ire Olohun Allaah tie ni eyin nse, Iwo lo da a wo mi, mo nbeere awon ore Re ni odo Re ati awon oore ti won se aso yi fun un, atipe mo fi E wa iso kuro nibi aburu re ati aburu ti won se e fun. (1) .................... (1) Abu Daaud, pelu number 4020, ati At-tirmidhiy, pelu number 1767, ati Al-Bagawiy, 12/40, ki o si tun wo: Mukh'tasoru Shamaailit Tirmidhiy ti Alfa wa Al-Albaaniy se, oju ewe 47

API