Adura eniti o ba sin

Ti enikookan yin ba sin, ko ya so pe: Alhamdulillaah ope ni fun Olohun, ki omo iya re tabi ore re o wa so fun un pe: Yarhamukalloohu Olohun a ke e, ti o ba wa so fun un pe: Yarhamukalloohu, ki o ya so pe: Yahdiikumulloohu wa yuslihu baalakum Olohun a fi yin mona yio si tun alamori yin se.

API