Adura leyin igbati a ba pari aluwala

Mo jeri pe ko si Oba kan ti ijosin to si ayafi Allaah ni oun nikan, ko si orogun fun un, atipe mo jeri pe dajudaju Anabi Muhammad erusin Olohun ni ojise Re si ni. (1) ................................... (1) Muslim, 1/209, pelu number 234.

Ire Olohun semi ni ara awon ti o maa tuuba, atipe semi lara awon ti o maa se imara. (1) ........................... (1) At-Tirmidhiy, 1/78, pelu number 55, ki o si tun wo: Sohiihut Tirmidhiy, 1/18.

Mimo fun Ire Olohun Oba ati pelu eyin Re, mo jeri pe ko si eniti ijosin to si ayafi Iwo, mo nwa aforijin Re, mo si ntuuba losi odo Re. (1) ....................... (1) An-Nasaaiy ninu Amalul yaomi wal lailah, oju ewe 173, ki o si tun wo: Irwaaul Galiil 1/135, ati 3/94.

API