Adura ti wa se fun eniti o ba bu

Anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – so pe: Ire Olohun eyikeyi muumini ti mo ba bu u se e ni ohun ti yio fi sun mo O fun un ni ijo agbende.

API