Adura sise nibi gbigbo kiko akuko ati ihan ketekete

Ti e ba gbo ti akuko ba ko ki e ya beere lowo Olohun ninu ola Re; toripe dajudaju o ri malaika kan ni ti e ba si gbo ti ketekete han ki e ya wa iso pelu Olohun kuro lodo shaitoon tori dajudaju o ri shaitoon kan ni.

API