Adura fifi ori kanle

(Mimo fun Oluwa mi eniti o gaju). Ao wi i ni eemeta (1) ............................. (1) Awon ti won se tira Sunan ni won gbe e jade, ati Ahmad: Abu Daaud, ni number 870, ati At-Tirmidhiy, number 262, ati An-Nasaai, number 1007, ati Ibnu Maajah, number 897, ati Ahmad, number 3514, ki o si tun wo: Sohiihut Tirmidhiy, 1/83.

(Mimo fun Ire Oluwa mi, Ire Oluwa, Oluwa wa ati pe pelu eyin Re, Ie ni Oluwa fi orijin mi) (1) ................................. (1) AL-Bukhaari, pelu number 794, ati Muslim, pelu number 484, atipe o ti saaju pelu number 34.

(Ire eniti oni afomo tabi eyin Ire eniti omo kanga Oluwa awon molaika ati Jubril) (1) ...................... (1) Muslim, 1/533, pelu number 487, ati Abu Daaud, pelu number 872, o si ti saaju pelu number 35.

(Ire Oluwa, Ire ni mo fi orikan le fun, Ire si ni mo gbagbo, Ire ni moju wo juse sile fun ori mi kanle si eniti o se eda re ti o si ya aworan re, ti o si yo igboran re ati iriran re, ibukun ni fun Allah eni ti o dara ju ni adeda) (1) ............................. (1) Muslim, 1/534, pelu number 771, ati eyiti o yato si i.

(Mimo fun eni ti O ni ipa ati ola ati motomoto ati titobi) (1) ........................... (1) Abu Daaud, 1/230, pelu number 873, ati An-Nasaai, pelu number 1131, ati Ahmad, pelu number 23980, ti Al-Albaaniy si so pe o ni alaafia ninu tira Sohiihu Abi Daaud, 1/166, atipe sise alaye agbejade re ti saaju pelu number 37.

(Ire ni Oluwa fi gogbo ese mi jinmi, eyi ti o pamo ati eyi tio han, eyi fin kere ati eyi nto po, ati ibere re ati opin re ati eyi ti o gbangba ati koro re) (1) ......................... (1) Muslim, 1/230, pelu number 483.

(Ire Oluwa mo wa iso pelu iyonu Re kuro nibi ibinu Re pelu amoju kuro Re kuro ni bi iya Re, atipe mofi E wa iso kuro nibi iya Re, mio le se ounka eyin fun O, gegebi O se se e fun ara Re) (1) ......................... (1) Muslim, 1/352, pelu number 486.

API