Adura ti eniti o ba ri eniti won fi adanwo kan maa nse

Ope ni fun Olohun Oba ti O mu mi lara da kuro nibi nkan ti O fi se adanwo fun o, ti O si dami lola lori opolopo ninu awon nkan ti o da ni ti didalola.

API