Adura ijoko laarin iforikanle meji
(Ire Oluwa mi fi ori jin mi, Ire Oluwa mi fi ori jin mi) (1)
..........................
(1) Abu Daaud, 1/231, pelu number 874, ati Ibnu Maajah, pelu number 897, ki o si tun wo: Sohiihu Ibni Maajah, 1/148.
(Ire Oluwa fi ori jinmi atipe ki o kemi atipe ki o fimi mona atipe kio bukun mi, ki o si fun mi ni alaafia, kio si fi arisiki fun mi kio si gbemiga) (1)
...............................
(1) Awon ti won se tira Sunan ni won gbe e jade ayaafi An-Nisaai: Abu Daaud, 1/231, pelu number 850, ati At-Tirmidhiy, pelu number 284, ati 285, ati Ibnu Maajah, pelu number 898, ki o si tun wo: Sohiihut Tirmidhiy, 1/90, ati Sohiihu Ibni Maajah, 1/148.