Adura ti eeyan ma nse nigbati eeyan ba sinu lodo awon ara ile kan

Awon alaawe sinu lodo yin, awon eniire si je ounje yin, awon malaika si ti se adura fun yin.

API