Adura ti a ma nse ni ojo Arafa

Anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – so pe: Adua ti o loore ju ni adua ijo Arafa atipe eyiti o loore tie mi pelu awon anabi to saaju mi so ni: laa ilaaha illal laahu wahdahu laa shariika lahi, lahul mulku wa lahul amdu wa huwa ala kulli shaihin qodiir Ko si olujosin fun Kankan ayaafi Alloohu nikansoso ko si akegbe fun Un, ti E ni ola nse, ti E sini eyin nse, Oun sini oba ti o ni ikapa lori gbogbo.

API