Adura ti a maa nse ti aba lo se abewo si alaare

O o nii ri aburu, aisan yii yoo je afomo kuro ninu ese fun e ti Olohun ba fe.

Mo nbe Olohun ti O tobi, Oba ti O ni aga Alaarashi ti o tobi, ki O se iwosan fun o

API