Adura gbigborikuro ni rukuhu

(Oluwa gbo ohun emi ti o yin) (1) .......................... (1) Al-Bukhaari pelu Al-Fat'hu, 2/282, ni number 796.

(Ire Oluwa wa atipe tire ni eyin, eyin ti o po ti o dara ti o si ni alubarika ninu) (1) ....................... (1) Al-Bukhaari pelu Al'fat'hu, 2/284, ni number 796.

(Ohun ti okun awon sanmo ati ohun ti o kun ile ati ohun to wa larin awon mejeeji ati kikiun ohun ti O ba nfe ni eyin re, Ire ni eni ti o si ati aponle ohun ti o leto ju ti eru n so atipe gbogbo wa eru Re niwa. Ire Oluwa kosi oludena fun nkan ti o ba funi atipe kosi ollufun nini ohun ti o ba kofuni atipe agbara kole wulo fun alagbara odoRe ni agbara wa atipe odo Re ni agbara ti nwa) (1) ................................ (1) Muslim, 1/346, ni number 477.

API