Adura ti a ma nse fun eniti o ba wo aso tuntun

O lo o gbo atipe Olohun Oba yio si fi omiran paro. (1) ......................... (1) Abu Daaud lo gbe e jade. 4/41. ki o si tun wo: Sohiihu Abi Daaud, 2/760

Wo aso tuntun ki o si maa semi ni eni tyin, ki o si ku ni shahiidi. (1) ...................... (1) Ibnu Maajah, 2/1178, pelu number 3558, ati Al-Bagawiy, 12/41, ki o si tun wo: Sohiihu Ibnu Maajah, 2/275.

API