Ohun ti eniti o ba kefin irora kan ni ara re maa se ati ohun ti o maa so

Gbe owo re le ibiti o nro e ninu ara re ki o wa so pe: Bismillaah ni eemeta, ki o tun wa so ni eemeje pe: Ahuudhu bil laahi wa qud'rotihi min sharri ma ajidu wa uhaadhir. Mo fi Olohun wa iso ati ikapa re kuro nibi ohun mo nri ati ohun ti mo nsora fun.

API