Sise asalatu fun – ki ike ati ola Olohun maa ba a – leyin Atayah

(Ire Oluwa se asalatu fun anabi Muhammed ati awon ara ile anabi Muhammed gege bi osese ike fun anabi Muhammed ati awon ara ile anabi Muhammed gege bi osese ike fun anabi Ibrahim ati awon ara ile Ibrahim dajudaju Iwo ni Oba eleyin to gbongbon, Ire Oluwa se ibukun fun anabi wa muhammed ati awon ara ile anabi muhammed gege bi osese ibukun fun anabi Ibrahim ati awon ara ile anabi dajudaju Ire ni Oba eleyin, Oba ti o gbongbo) (1) ............................... (1) Al-Bukhaari pelu Al-fat'hu, 6/408, pelu number 3370, ati Muslim, pelu number 406.

(Ire ni Oluwa se ike fun anabi muhammed ati awon iyawo re ati awon aromodomo re gege bi ose se ige fun anabi Ibrahim ati awon iyawo re ati awon aromodomo re gege bi osese ibukun anabi Ibrahim dajudaju Ire ni Oba eleyin Oba to gbongbon) (1) ................................. (1) Al-Bukhaari pelu Al-fat'hu, 6/407, pelu number 3369, ati Muslim, 1/306, pelu number 407, atipe gbolohun yi tie ni.

API