Adura wiwo mosalasi

(Yio bere pelu ese otun re)(1) yio wa so pe: (Mo wa iso pelu Olohun Oba ti o tobi, ati pelu iwaju Re alaponle, ati agbara Re ti o ti nbe tipe kuro ni odo shaytaan eni eko)(2) [mo bere pelu oruko Allaah, ki ike](3) [ati ola si maa ba ojise Olohun](4) (Ire Oluwa si ilekun ike Re fun mi)(5) .............................. (1) Latara gbolohun Anas omo Maalik - ki Olohun yonu si i -: (ninu Sunnah nipe ti o ba ti wo masalaasi ki o bere ese re otun, ti o ba si ti jade ki o bere pelu ese osi re), Al-Aakim ni o gbe e jade, 1/218, ti o si so wipe o ni alaafia lori majemu Muslim, ti Ad-dha'abiy si fi ara ma an, atipe Al-Baiaqiy naa gbe e jade, 2/442, ti Al-Albaaniy si so wipe o daa ninu tira Silsilatul Ahaadeethis Sohiiha, 5/624, pelu number 2478. (2) Abu Daaud, pelu number 466, ko si tun wo: Sohiihul Jaamihu. (3) Ibnus Sinniy gba a wa, pelu number 88, atipe Al-Albaaniy so pe o daa ninu tira Ath-Thamarul Mustatoob, oju ewe 607. (4) Abu Daaud, 1/126, pelu number 465, ko si tun wo: Sohiihul Jaamihu, 1/528. (5) Muslim, 1/494, pelu number 713, ati ninu Sunanu Ibnu Maajah lati inu Hadiith Faatimah: (Ire Olohun se aforijin awon ese mi fun mi, ki O si tun si awon ile ike Re fun mi ), atipe AL-Albaaniy so pe o daa latari awon ti o kun un lowo. wo: Sohiihu Ibnu Maajah, 1/128-129.

API