Adura fifori kanle Tilawa Al-quran

(Orimi kanle fun eni ti o da ti oo si yo igbora Re ati iriran Re pelu agbaraRe pelu ogbon Re ati agbara Re ibukun ni fun Allah eniti o dara ju ni adeda) (1) .......................... (1) At-Tirmidhiy, 2/474, pelu number 3425, ati Ahmad, 6/30, pelu number 24022, ati Al-Aakim, ti o si so pe o ni alaafia, atipe Ad-Dha'biy naa si fi ara ma an, 1/220, atipe alekun tie ni, atipe Aayah number 14 wa ninu Suuratul Muh'minuun.

(Ire Oluwa fi ko akosile leda fun mi ni odo Re atipe figbe ese kuro fun mi atipe fise nkan ipamo atipe bami se nkan ipamo ni odo Re atipe tewo gba ni owo mi, gege bi ose tewo gba ni odo eru Re anabi Dahud) (1) ........................ (1) At-Tirmidhiy, 2/473, pelu number 579, ati Al-Aakim o si so pe o ni alaafia ti Ad-Dha'biy naa si fi ara ma an, 1/219.

API