Bawo ni anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – se ma nse afoma?

Egbawa yi wa lati odo Abdullaah omo Abbaas – ki Olohun yonu si awon mejeeji – o so pe: Mo ri anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – ti nse afomo pelu owo re. Ninu afikun kan: pelu owo otun re.

API