Adura ti eeyan maa nse nigbati eeyan ba gbo gbigbo gbigbo awon aja ni oru

Ti e ba gbo gbigbo awon aja ati ihan ketekete ni oru ki eya wa isora pelu Olohun kuro lodo won; toripe dajudaju won nri ohun ti eyin o ri ni.

API