Adura ti a maa nse ti a ba lo se ibewo awon saare

Alaafia Olohun ki o maa ba eyin olugbe ibi ninu mumini ati musulumi, bi Olohun ba fe awa naa fee ba yin nibi, Olohun yio ba ni ke awon olugbawaju inu wa ati awon ti won nbo leyin, A be Olohun fun awa ati eyin naa ini amojukuro Olohun

API