Ohun ti eeyan maa nso lati da eti awon alagidi ashaitaani pada

Mo wa isora pelu awon gbolohunOlohun ti o pe ti o se wipe ko si enirere kan tabi eniibu kan ti o tayo re: kuro nibi aburu ohun ti O da, ati ohun ti O so di bibe, ati nibi aburu ohun ti nsokale lati sanmo, ati nibi aburu ohun ti ngun sanmo lo, ati nibi aburo ohun ti o da sile, ati nibi aburu ohun ti njade lati inu re, ati nibi aburu fitina oru ati osan, ati nibi aburu gbogbo awon isele ti nsele loru yato si isele daada Ire Oba Ajokeaye.

API