Adura eniti o fe iyawo ati rira nkan ogun

Ti enikan ninu yin ba fe omobinrin, tabi ti o ba ra eru kan, ki o ya so pe: Ire Olohun dajudaju emi nbeere lowo Re daada re, ati daada ti O da mo on, mo wa nfi O wa iso kuro nibi aburu re, ati aburu ti O da mo on, ti o ba tun wa ra rakunmi kan ki o ya gba sonso ike eyin re mu, ki o si so iru adua oke yi.

API