Ohun ti eniti Oba lala kan maa se

Yio ta oda si egbe osi re nigba meta Yio fi Olohun wa isora kuro nibi odo esu ati aburu nkan ti o ri…. Yio se eleyii ni emeta otooto Ko ni so fun eni Kankan Yio paro egbe ti o fi sun

O le dide lati kirun ti o ba fe be

API