Adura Rukuhu
(Mimo fun Oluwa mi ti o tobi). Ni eemeta (1)
...........................
(1) Awon ti o se tira Sunan ni o gbe e jade, ati Ahmad: Abu Daaud, pelu number 870, ati At-Tirmidhiy, pelu number 262, ati An-Nasaai, pelu number 1007, ati Ibnu Maajah, pelu number 897, ati Ahmad, pelu number 3514, ki o si tun wo: Sohiihut Tirmidhiy, 1/83.
(Mimo Re Iwo Oluwa wa ati pelu eyin Re, Oluwa fi orijin mi) (1)
.........................
(1) Al-Bukhaariy, 1/99, pelu number, 794, ati Muslim, 1/350, pelu number 484.
( Ire ni Oba eleyin eniti o mo kanga Oluwa awon molaika ati Jubril) (1)
..........................
(1) Muslim, 1/353, pelu number 487, ati Abu Daaud, 1/230, pelu number 872.
(Ire Oluwa ni morukuhu fun IRe nimogbagbo atipe IRe ni moju wo juse fun. Igbonran mi lati tetisile fun ati iriran mi ati opolo mi ati egun mi ati iriran mi [ati ohun ti ese mi duro lelori]) (1)
...........................
(1) Muslim, 1/534, pelu number 771, ati awon meerin ninu awon ti won se tira sunan ayaafi Ibnu Maajah: Abu Daaud,, pelu number 760, ati number 761, ati At-Tirmidhiy, pelu number 3421, ati An-Nasaai, pelu number 1049, atipe ohun ti o wa laarin orun mejeeji gbolohun Ibnu Khuzaimah ni, pelu nnumber 607, ati Ibnu Ibbaan, pelu number 1901.
(Mimo fun eni ti O ni ipa ati ola ati motomoto ati titobi) (1)
.............................
(1) Abu Daaud, 1/230, pelu number 873, ati An-Nasaai, pelu number 1131, ati Ahmad, pelu number 23980, atipe afiti re si daa.