Ohun ti a maa n fi wa isora fun omo ti a ba bi

Ojise Olohun maa nwa isora fun Hassan ati Hussein, ki Olohun bani yonu si awon mejeeji pelu ko so bayii wipe: Mo nfi awon gbolohun Olohun Oba ti Ope wa isora fun eyin mejeeji kuro ni odo shaytan (esu) ati eranko tabi kokoro oloro, ati kuro nibi gbogbo oju-koju.

API