Adura irun pipe

Yio maa so iru nkan ti eniti o nperun nso, ayafi igbati oba de ibi ti (ayalal salat, wa ayalal falal) yo wa ma so ni be pe: (lalaola wala quwwata illaa billaah kosi ogban ko sisi agabra ayafi pelu Allah)(1) ................................ (1) Al-Bukhaariy, 1/152, pelu number 611, ati number 613, pelu Muslim, 1/288, pelu number 383.

(atipe emi jeri pe kosi eniti ijosin to si ju Allah lo ni Oun nikan kosi orogun fun Un, atipe anabi Muhammed erusin Re ni ojise Re si ni pelu, mo yonusi Allah ni oluwa atipe moyonusi Muhammed ni ojise atipe moyonu si Islaam ni esin) (1) (yio ma so iyen leyin igbati enitoun perun ba so pe Laa ilaaha illal laah) (2) ................................ (1) Muslim, 1/290, pelu number 386. (2) Ibnu Khuzaimah, 1/220.

(Yo wa so asalatu fun anabi ki ike ati ola olohun ko maba leyin igbati o ba pari dida aperun loun) (1) ........................... (1) Muslim, 1/288, pelu number 384.

(Ire Oluwa Oba ti oni ipepe ti o pe yi ati irun ti won gbe duro yi fun anabi wa Muhammad ni aga wasila ati ola, atipe gbe e dide ni aye eleyin eyiti O ti se adehun re fun un, dajudaju Ire ki ye adehun) (1) ........................... (1) Al-Bukhaariy, 1/152, pelu number 614, gbolohun ti nbe ninu orun mejeeji yen ti Al-Bai'aqiy, 1/410. ti Alufa agba Abdul Azeez omo Baaz so pe o daa - ki Olohun ke e - ninu tira Tuhfatul Akh'yaar, oju ewe 38.

(yio se adura fun arare lerin irun pipe ati ikaamo, toripe dajudaju adura sise nigbayen won o ni da a pada) (1) ........................ (1) At-Tirmidhiy, pelu number 3594, ati number 3595, ati Abu Daaud, pelu number 525, ati Ahmad, pelu number 12200, ki o si tun wo: Irwaaul Galiil, 1/262.

API