Ohun ti Musulumi maa so nigbati won ba nse afomo re

Ire Olohun ma fiya jemi pelu ohun ti wo nso, wa fi ori jin mi nibi ohun ti won o ma, wa semi ni eeyan daada ju bi won se lero lo.

API