Ohun ti eniti Oba da ese yio so ati ohun yio se

Ko si eyikeyi ninu eru kan ti o ba da ese kan, to ba wa se aluwala daadaa leyin eleyi yio dide, yio si gbe rakah irun meji duro leyin eleyii yio wa aforiji Olohun, ko nii se gbogbo eleyii ayafi ki Olohun se aforijin ese re

API