Adura ti eniti o wa nile maa nse fun arin irinajo

Mo fi esin re le Olohun lowo, ati afunnso re, ati awon igbeyin ise re.

Olohun a fun o ni iberu Re, yio si fi ori ese re jin o, yio si ro daada fun o ni ibikibi ti o ba wa.

API