Adura ti eniti o ba nbere ki aburu ma kan nkan pelu oju re ma nse

Ti enikookan yi ba ri ohun ti o wu u ni ara omoya re, tabi ni odo ara re, tabi nibi dukia re ki o ya se adua alubarika si i toripe ojukoju nbe.

API