Adura wiwo aso

Ope ni fun Allaah ti o fi ewu yi wo mi ti o se pese re fun mi laise pelu ogbon tabi agbara lati odo mi. (1) ...................... (1) Awon alfa ti won se tira Sunan ni won gbe e jade ayafi Al-Nasai nikan: Abu Daaud, pelu number 4023, ati Al-Tirmidhiy, pelu number 3458, ati Ibnu Maajah, pelu number 3285, Al-Albaaniy si so wipe o daa ninu: Irwaahul Galiil

API