Adura ti a ba fe jade kuro ninu ile

Pelu oruko Olohun, mo gbarale Olohun, ko si si ikapa ati agbara kankna ayafi pelu Allaah. (1) .......................... (1) Abu Daaud, 4/325, pelu number 5095, ati At-Tirmidhiy, 5/490, pelu number 3426, ki o si tun wo: Sohiihut Tirmidhiy 3/151.

Ire Olohun Oba dajudaju emi sa di O nibi ki nsonu tabi ki won somi nu, tabi ki nye ese gere tabi ki won yemi lese gere, tabi kin se abosi eniyan tabi ki won se abosi simi, tabi ki nwu iwa aimokan tabi ki won wu iwa aimokan simi. (1) ............................................. (1) Awon ti won ni tira Sunnah: Abu Daaud, pelu number 5094, ati At-Tirmidhiy, pelu number 5501, ati An-Nasaaiy, pelu number 5501, ati Ibnu Maajah, pelu number 3884, ki o si tun wo: Sohiihut Tirnidhiy, 3/152, ati Sohiihu Ibnu Maajah, 2/336.

API