Adura jijade kuro ni masalaasi

(Yio bere pelu ese osi re)(1) yio wa so pe: (Pelu oruko Allaah, ki ike ati ige ko si maa ba ojise Olohun, Ire Oluwa dajudaju emi nbeere ninu ola Re, Ire Oluwa somi kuro ni odo shaitaan eni eko)(2) .................................. (1) Al-Aakim, 1/218, ati Al-Bai'aqiy, 2/442, ti Al-Albaaniy si so pe o daa ninu tira Silsilatul Ahaadiithis Sohiihah, 5/624, pelu number 2478, atipe sise alaye agbejade re ti saaju. (2) Wo sise alaye agbejade awon egbawa hadiith ti o saaju yi nibi adua wiwo masalaasi, number (20) atipe alekun: (ire Olohun so kuro lowo Ash-shaitaan eni eko) je ti Ibnu Maajah. wo: Sohiihu Ibnu Maajah, 1/129.

API