Adura gigun nkan

Pelu oruko Olohun, eyin ti Olohun ni, Mimo fun eniti o ro eleyi fun wa ti o si je wipe awa o ni ikapa le e lori. Atipe dajudaju awa odo Olohun wa ni a maa seri pada si. Gbogbo eyin ti Olohun ni, gbogbo eyin ti Olohun ni, gbogbo eyin ti Olohun ni, Olohun Oba tobi, Olohun Oba tobi, Olohun Oba tobi, mimo Re Olohun Oba, dajudaju emi ti se abosi emi ara mi, wa se aforijin fun mi, toripe tajudaju ko si eniti o le se aforijin awon ese ayafi Iwo.

API