Adura ti arin irinajo ma nse nigbati o ba rin ni asiko saari

Olugbo oro kan mu eyin mi fun Olohun de etigbo elomiran, ati dida adanwo Re lori wa, Ire Olohun wa wa pelu wa, ki O si se ola fun wa, mo je eniti nwa iso pelu Olohun kuro nibi ina.

API