Adura ti a maa nse fun eniti o fun wa ni ounje tabi mimu

Olohun bani se jije fun eni to fun mi ni jije, ba ni se mimu fun eni to fun mi lomi mu.

API