Adura ti eeyan maa nse ti eyan ba ni ipaya kan ni oju orun abi eniti won bafi adanwo ipa aayun se

Mo n fi awon gbolohun Olohun ti o pe wa isora kuro nibi ibinu Re ati ifiya jeni Re, ati aburu awon eru Re, ati nibi royiroyi awon esu ati ki won wa si odo mi.

API